Eniola Ogungbe is a spirit filled Gospel music minister,recording artiste, a lead vocalist, composer and praise lover, whom God has been using to bless this generation through her ministrations.
'Oba Ni O' is an inspirational song exalting God and precisely giving reference to his names, kingship and what he is capable of doing at the mention of those names.
Written and composed by Eniola Ogungbe.
Produced by Emmanuel Aboluwade.
Lyrics
Oba Ni O
Chorus
Oba ni o laye lorun kos'oba b'ire
atobatele k'oto j'oba Olorun agbaye
Yawhe, most high l'oruko re ayin o
Emmanuel, wonder igbala wa
Ema ma se
Verse 1
Oba t'oti wa k'aye to wa
Ipinle ohun gbogbo
Alabo, olufe, ol'oruko egbaagbeje
n o p'oruko re
k'aye le mo b'oti tobi to
kari-ola, kari-ile o
dansaki re o baba
Chorus
Oba ni o laye lorun kos'oba b'ire
atobatele k'oto j'oba Olorun agbaye
Yawhe, most high l'oruko re ayin o
Emmanuel, wonder igbala wa
Ema ma se
Verse 2
Oro ti ngbe oro mi
Ijinle t'oju imule lo
Atobiju, ajunilo, adakeja, ajamajebi
Oruko re le ni'gba
mo wo yika aye, o o l'afiwe
ti m'ba ni nka'ruko re
ile asu, ile amo
Chorus
Oba ni o laye lorun kos'oba b'ire
atobatele k'oto j'oba Olorun agbaye
Yawhe, most high l'oruko re ayin o
Emmanuel, wonder igbala wa
ema ma se
Bridge
Omimi mi'le mi'gi oko l'olruko to n je
Ogbon t'oju ogbon lo
Ologbon to mu omi wo'nu agbon
Adanimadale eni
Ikoko ti nbo gbogbo agbaye
Afunni ma si'regun o
Oba oba oba ni
Call: E bami pe o
Response: Oba ni
Call: E pee o
Response: Oba ni
Call: Oni'budo ogo
Response: Oba ni
Call: Akikitan, ayinyintan o e
Response: Oba ni
Call: Oni majemu lae lae
Response: Oba ni
Call: Kakaki orun
Response: Oba ni
Call: Aran ma pada tu mo, atu ma pada ran
Etc...
DOWNLOAD HERE
No comments:
Post a Comment